Jowo gba adura soke te le mi lati inu okan re wa:
Baba ni orun
Mo too wa ni oruko Jesu
Mo gbagbo pe Jesu ni ayanfe omo re kansoso.
Mo gbagbo pe oruko re ni oruko kan soso ni orun
ati ni aye nipa eyi ti a le figba mi la.
Mo gbagbo wipe o ran nitori mi
Mo gbagbo pe o ku fun mi
Mo gbagbo pe eje re bo gbogbo awon ese mi
Ati pe mo ronupiwada mo yi pada kuro ninu igbe
aye ibi mi atehin wa
Jesu Oluwa, mo fi fun o bayi,
Gbogbo okan mi.
Ati gbogbo aye mi.
Mo fi o se Oga aye mi, Lati oni lo no ma se nkan
ni ona tire!
Wa sinu aye mi bayi Jesu Oluwa ki o si kun mi
pelu Emi re.
Jowo so mi di eda titun
Je ki o di mimo bayi wipe mo ti di kristiani
Je ki o di mimo bayi, wipe mo ti di atunbi!
Ati gbami la,
Mo ti gba isegun!
Mo di ominira!
Mo wa laaye titilai!
Mo n lo sorun!
Mo se orun apadi!
Jeki o ki mimo bayi,
Pe mo je omo Olorun
E se Jesu!
E se Oluwa!
Kun mi bayi pelu emi mimo Re.
Se aye mi ni majemu fun ore-ofe igbala re
Ni oruko Jesu
Amin
Halleluyah! O ti di eni igbala! Kaabo si idile
Olorun!