Ogbon ti aye n fe ki a gbagbo pe gbogbo esin ti
o wa ninuaye je nkan kan naa, pe gbogbo ona ni o
losi orun, laika ohun tabi eni ti a gbagbo ninu
re. Sugbon se eleyi je otito bii?
Jesu wi pe, Emi li ona, ati otito, ati iye: ko
si eni ti o le wa sodo Baba, bikose nipase mi.
Johannu 14:6
Ise 4:12 wipe ko si igbala lodo elomiran :
nitori ko si oruko miran labe orun ti a fifunni
ninu eniyan; nipa eyiti a le fi gba wa la.
Loni eyin ore mi, mo gbodo so oju abe niko. Ti
oko ba ni Jesu ninu okan re, a ko le gba o la!
Laisi Jesu ko si igbala. O pari. Mo toro gafara!
Sugbon enikan gbodo le feran re labe wipe a le
so fun o, ati pe loni, mo jowo ara mi lati so
otito yi fun o.
Sugbon, o wipe Emi ti je kristiani tele! Idile
kristiani ni, mo ti dagba. Awa ki se elesin
Budha, Musulumi, Juu tabi ti Hindu, a si ma n’
lo soosi ni akoko Ajinde ati keresimesi, nitori
naa kristiani ni wa!
Se o mo wipe Bibeli ko so nibi kankan! pe o le
de orun tabi gba iye ayeraye nipa pipe ara re ni
kristiani?
O dara o dahun wipe, sugbon ile-iwe ti awon
kristiani da sile nimo lo. Mo lo si kilase
katikisun {tabi ile eko ojo isinmi ti satide
tabi ti Sunday} ni gbogbo ojo aye mi.mo ma n wo
agbelebu {tabi kristofa mimo} si orun mi!
Eleyi dara, sugbon se o mo pe Bibeli ko so wipe
o le de orun tabi ni iye aini pekun nipa lilo si
soosi, katikisi, ile-eko ojo isinmi ti satide
tabi ti Sunday taabi wiwo agbelebu tabi kristofa
mimo si orun re?
O daa… mo ma n ka Bibeli, mosi ma n gbadura
lojojumo! Inu mi dun wipe o n se bee!
Ati wipe nitori ti o n se eyi, o timo wipe
Bibeli ko so wipe o le de orun ati ki o ni iye
ayeraye nipa adura ati eko Bibeli nikan!
O dara. Sugbon mo feran Olorun. Eyi ba mi leru.
Sugbon n je o ma pe awon Onisunmoni
mokandinlogun ti won wa oko ofurufu kolu ile
itaja Agbaye ati ti ile ijoba Pentagon ni ojo
kokanla osu kesan, odun 2001, naa so wipe awon
na feran Olorun?
Nje o mo wipe Bibeli ko so ohunkohun nipa dide
orun ati gbigba iye ayeraye. Nipa ife re fun
Olorun nikan?
Sugbon enikan so fun mi nigba kan pe ti mo ba
gbagbo pe Jesu Kristi ni omo Olorun, mo le lo si
orun, ki nsi ni iye ayeraye.
Je ki n tun so oju-abe niko ? Bibeli wipe awon
emi esu papaa gbagbo pe Jesu kristi ni omo
Olorun {Jakobu 2:19}, ati wipe satani papaa
gbagbo pe Jesu ni omo olorun! Bibeli wipe Jesu
ti pese adagun ina ayeraye fun esu ati awon
angeli re {matt.25:41}! Igbagbo won ninu Jesu o
daju ko le mu iye ayeraye wa fun won l’orun!
Sugbon mo ti pa gbogbo o fin mewewa mo ni gbogbo
ojo aye mi!
Eleyi lagbara! Sugbon se o mo wipe Bibeli ko
wipe pipa ofin mewa mo yoo mu o gba iye ayeraye?
Eyin ore mi, ni kukuru ko si ninu iwe na!
Eje ki a gbe itan Nikodemu wo ni kiakia.
Nikodemu je farisi eni ti npo ofin mo gidigidi.
O ko Bibeli sori, o n koo lorin, o si n koni ni
oro olorun ni gbogbo ojo isinmi. Eniyan a tiro
wipe nigbati Nikodemu wa si odo Jesu, pe Oluwa
yoo yin, ki o si wipe o kare Nikodemu! Orun n
duro de o!
Sugbon eleyi ko ni Oluwa so fun Nikodemu rara.
Dipo eyi o so fun Nikodemu wipe ayafi ti a ba bi
nupa omi ati imi, oun ko le wo inu ijoba Olorun.
O so fun Nikodemu, O GBODO DI ATUNBI {Joh. 3:3}.
Kinni eyi tumo si fun o ? o tumo si pe o gbodo
di atunbi lati losi orun ati lati ni iye ayeraye!
Ni bayi kinni o tumo si lati di atunbi?
O tumo si wipe o gbodo fun Jesu ni gbogbo okan
re ati gbogbo aye re. Bi o ti rorun to niyen! Ti
o ko ba ti se bee, a ko ti gba o la.{lekan si mo
toro aforiji sugbon enikan gbodo feran re tobe
lati so fun o}
Lati Genesisi 1: titi de awon aworan ti o wa
lehin Bibeli, Oro Olorun ko yi pada! O gbodo fun
olorun ni gbogbo okan re ati gbogbo aye re.
Eleyi tumo si wipe Jesu gbodo je Oluwa aye re. O
tumo si wipe iwo yoo fi se Oga re! Ti o ko batii
fi se oga lori aye re, a je wipe o ko ti di eni
igbala. Bi o se ri niyen.
Sugbon mo gba adura igbala yen ni ibi isin
itagbangba Billy Graham {tabi isin ikore ita
gbangba kan}! Mo dahun si ipe si ifi aye eni fun
Jesu ni soosi ni akoko kan!
Eyi dara pupo! Sugbon se o ngbe aye ni ibamu
pelu adura naa?
Nje o mo wipe Bibeli ko so nibi kankan pe gbigba
adura kan yoo mu o do orun?
O daju, adura naa se pataki, sugbon se o fun un
ni gbogbo okan re ati gbogbo aye re nigba ti o
gba adura naa? Nje o fi se oga aye re? Tabi
adojutofo ina kan ni o fun o ni igbekele lati
gbe igbe aye re bi o ti wu o laisi eru lilo si
orun apadi?
Se ki n so ohun kan fun o? Kii sise ba yen.
Ibasepo patapata pelu Olorun ni tabi ki a ma se
rara. Yala ki o fun gbogbo okan ati aye re, fun
un ati ki o fi se oga lori aye re, tabi ki o ma
di eni igbala! {Ati wipe enikan gbodo feran re
to lati so otito fun o}
Eyin ore mi, akoko yi ni fun o lati ye ara re wo!
Oni ni ojo igbala re. Laipe n o fun o ni anfani
lati wa ni ibare pelu olorun, lati fi gbogbo
okan re ati gbogbo aye re, ati ki o gba
idaniloju iye ayeraye ni orun
Nje tanio ye ki o dahun si ipe yii?
Je ki n dahun nipa bibere awon ibere die:
Nje o ti fi igba kankan fun Jesu ni gbogbo okan
re ati gbogbo aye re? Bi beeko, a je wipe oni ni
ojo igbala re!
Nje o ti fi igba kanfi Jesu se oga aye re? Bi
beeko, a je wipe oni ni ojo igbala re!
Nje o ti ngbe aye re fun ara re, kii sefun Jesu?
Bi o ba ri bee a je wipe oni ni ojo igbala re!
Nje o ti n sa kuro lodo olorun dipo sisa lo sodo
Olorun? Bi o ba ri bee a je wipe oni ni ojo
igbala re!
Se ori ni oti ni Jesu dipo okan re? Ti o ba ri
bee a je wipe oni ni ojo igbala re!
Ti okankan ninu awon ohun ti a ko yi ba se
apejuwe re, N o fe lati gba adura kan pelu re.
Ti ko ba da o loju pe eyi se apejuwe. Rii daju!
Ti o n ba nroo pe boya iwo ni mo nba soro. Iwoni
oni ni ojo igbala re!
Ti o ba ti se tan lati gba Jesu Kristi
nisinsinyi, gegebi Oluwa ati olugbala re, oga
re, lati fi gbogbo okan re ati gbogbo aye re fun
un nisinsinyi, jowo so wipe emi niyen! E sese se
apejuwe mi ni, ati pe mo Setan lati ba Jesu lo!
Halleluyah!
Ti o ba ti je ipe yii, jowo ba wa soro, lo ona
ti o wa ni isale