Check out our Video version of the Saviour’s Call
[Video Version] | [Français] | [English] |[Español] | [Yoruba] | [Duetsch] | [ខ្មែរ។] | [தமிழ்] | [বাংলা] | [Italiano] | [తెలుగు]
Adura:
Jowo gba adura soke te le mi lati inu okan re wa:
Baba ni orun
Mo too wa ni oruko Jesu
Mo gbagbo pe Jesu ni ayanfe omo re kansoso.
Mo gbagbo pe oruko re ni oruko kan soso ni orun ati ni aye nipa eyi ti a le figba mi la.
Mo gbagbo wipe o ran nitori mi
Mo gbagbo pe o ku fun mi
Mo gbagbo pe eje re bo gbogbo awon ese mi
Ati pe mo ronupiwada mo yi pada kuro ninu igbe aye ibi mi atehin wa
Jesu Oluwa, mo fi fun o bayi,
Gbogbo okan mi.
Ati gbogbo aye mi.
Mo fi o se Oga aye mi, Lati oni lo no ma se nkan ni ona tire!
Wa sinu aye mi bayi Jesu Oluwa ki o si kun mi pelu Emi re.
Jowo so mi di eda titun
Je ki o di mimo bayi wipe mo ti di kristiani
Je ki o di mimo bayi, wipe mo ti di atunbi!
Ati gbami la,
Mo ti gba isegun!
Mo di ominira!
Mo wa laaye titilai!
Mo n lo sorun!
Mo se orun apadi!
Jeki o ki mimo bayi,
Pe mo je omo Olorun
E se Jesu!
E se Oluwa!
Kun mi bayi pelu emi mimo Re.
Se aye mi ni majemu fun ore-ofe igbala re
Ni oruko Jesu
Amin
Halleluyah! O ti di eni igbala! Kaabo si idile Olorun!
Jowo je ki a mo! Jowo lo akoko kekere lati kowe si wa ki o si pin eri re pelu wa { To contact me click here }A o fe lati gbadura fun o ati ki a fi awon ohun ti yoo ran o lowo ninu irin ajo otun kristiani re sowo si o lofe.
Yin Oluwa o je idahun si adura.
Ki olorun ki o bukun fun o ore mi!
Lyn Chaffart
Oludari, ise iranse pepe
To contact me click here
Bere a o si fifun yin; wa kiri, enyin osiri; kankun a o si sii sile fun nyin.
Matt.7:7.